Tsung-Dao (T.D.) Lee | |
---|---|
Tsung-Dao Lee | |
Ìbí | 24 Oṣù Kọkànlá 1926 Shanghai, China |
Ará ìlẹ̀ | United States (1962-present) |
Pápá | Physics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of California, Berkeley Columbia University |
Ibi ẹ̀kọ́ | Zhejiang University National Southwestern Associated University University of Chicago |
Doctoral advisor | Enrico Fermi |
Ó gbajúmọ̀ fún | Parity violation Lee Model Non-topological solitons Particle Physics Relativistic Heavy Ion (RHIC) Physics |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize in Physics (1957) Albert Einstein Award (1957) |
Signature |
Tsung-Dao Lee tàbí T.D. Lee, (bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún Oṣù kọkànlá Ọdún 1926) jẹ́ aṣisẹ́olóhungidi ọmọ orílẹ̀ èdè China ará Amẹ́ríkà tó gba Ẹ̀bùn Nobel nínú ìmọ̀ Physics ní ọdún 1957.[1]